ITAN ILU ELESU
The story of the city of Elesu: the founder of Elesu is called AYELANGBE, Ayanlagbe is from the Basorun Fajimi Compound in Oranyan – Ibadan.
All Ayelangbe’s children that were brought to Elesu died, as result of this,
But Ayelangbe decided to go back to Oranyan, to the house where other Yerombi descendants were. He took Bankesa, the female child, with him to Ibadan and left the male child, Ifabunmi, with the Elesu man. Ifabunmi was left with the mother’s family and he lived there for the rest of his life. After many years they started calling the town
ITAN ILU ELESU (Oro soki lori idasile ilu ELESU)
Itan lori bi ase te ilu Elesu do, eni ti o te ilu elesu do ni oruko re n je AYELANGBE, Baba Ayelangbe wa lati, ILE BASHORUN ORANYAN ni Ilu Ibadan. Ayelangbe ohun wa lati Ilu ILORA ni Agbegbe ONIKOKO Idi le Onikoko. AYELANGBE je Jagunjagun. Eni ti o je ore Ayelangbe ti won pe ni MOJE, ohun lomu Ayelangbe de ibi ti won pe ni ILU ELESU Loni.
Ayelangbe, gege bi ase pe nje Jagunjagun, awon Alejo wa ma ba ni ibi ti o te do si, ninu alejo ti o te do si odore ibe ni won ti n pe Baba kan, ni BABA ELESU ti o ma fi EREE ELESU KAKIRI. Awon omo ti baba Ayelangbe ko de elesu, gbogbo omo na ku, igbati awon omo Baba na ku, owa pinu lati fi okan niniu awon omo Baba Elesu ti oje Obirin, omo obirin ti ofe bi omo meji fun, Okurin kan ati Obirin kan. Oruko awon omo na nje, BANKESA ni oruko obirin na, Okunrin na nje IFABUNMI.
Sugbon Ayelangbe pinu lati pada si ile BASHORUN Ni Ilu Ibadan, omu Bankesa obirin lo si Ibadan, o fi Ifabunmi si le pelu Baba Iya re ti won pe Ni Baba Elesu, bi Ifabunmi se ngbe pelu awon eyan Iya re ni ilu Elesu Ni ye. Leyin opolopo odun won wa bere si pe ilu na Ni ILU ELESU, nitori awon ni kan ni won ba ni ilu na.
BAALE ELESU: CHIEF GABRIEL AKINTOYE OLASUNBO FABUNMI

