BASORUN FAJIMI

The people who founded Basorun Fajimi Town are: Adeoye, Bangbaade and Basorun Fajimi, the town was previously known as Orogun, until the founders took possession of the area. After a while Basorun Fajimi started looking for some of the slaves he had kept in the town before going to war.  He later found them in a place called Alogilo close to Orogun river. Upon seeing Fajimi, the slaves were very happy and content because Fajimi is known for taking good care of his slaves and treating them as members of his own family.

Fajimi asked the slaves what they were doing at Orogun instead of where he had left them, they explained that they left the place he had situated them because some people were kidnapping and taking them to another place once he had gone to war. As a  result of this – they fled to find safety in Alogilo, close to the river.

After a little while, the Alaafin of Oyo enthroned Fajimi as Basorun of Yoruba land, one of the only four people to be conferred with such a powerful honor in Ibadan to date. As a result of this, Adeoye and Bangbade insisted that the name of Orogun Town be called  Bashorun Fajimi Town as a sign of respect and honor for his status in the land.

This was how the Town of Fajimi came to be.

ITAN ILU BASORUN FAJIMI

Awon ti won te ilu fajimi do ni, Adeoye, Bangbaade ati  Bashorun Fajimi, sugbon orogun ni a npe  ibe te le. Leyin odun di e ni fajimi bere si ni wa awon eru re ti o ko pamo ki oto lo si oju ogun, ibi ti o ti  ri won ni won pe ni Alogilo ni to si odo Orogun, nigbati o de ibe, ori wipe awon eru re ni won wa ni be, gbogbo won di de won surubo fajimi inu won dun pe olowo ori awon ti de nitori pe o mon n’toju awon eru re bi omo.

Fajimi bere lowo awon eru pe, kini won se ni ibi ti o ba won, won si se alaye irin ajo ti o gbe awon de Eba odo Orogun fun fajimi pe, awon kan wa ji won gbe ni igbati olo oju ogun, so da si ilu odi keji lati lo fi won se eru, nkan ti o je ki won sa lo si eba odo orogun lati ma gbe ni be niyen.

Leyin odun di e ni Alafin pe fajimi lati wa je Oye Bashorun Fajimi, ni Adeoye ati Bangbade se fi enu ko pe, ki Oruko Orogun Maje Bashorun Fajimi tori Ola Re po.

Bi fajimi se bere ni yi. 

BAALE Basorun Fajimi: CHIEF AMINU ADETONA ADEYEMI