Idile Fajimi; awon omo onile kijo, kijo!

Idile Fajimi; awon omo onile kijo, kijo!

Idile Fajimi; awon omo onile kijo, kijo!

E Kaabo si aaye idile Basorun Fajimi ti Ibadan, o jẹ idunnu fun wa lati ni yin nibi ati pe a ni ireti pe oruko a ti iwa abinibi ẹbi wa yi o jẹ anfani nla fun gbogbo eniyan.

Welcome to the royal website of Basorun Fajimi of Ibadan lineage. It is indeed a pleasure to have you here and we hope our shared family values will be of great benefits to all.